Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Tí o bá fẹ́ àlàyé lórí ọgbọ́n tí ọkọ tàbí aya kan lè dá sí àwọn ìṣòro tó máa ń wà nínú títọ́ ọmọ ẹni téèyàn ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́, lọ wo Ilé Ìṣọ́ March 1, 1999 tó ní àkòrí náà “Ìdílé Onígbeyàwó Àtúnṣe Bí Wọ́n Ṣe Lè Ṣàṣeyọrí.” Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é.