Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ìpínrọ̀ 3: Níwọ̀n bó ti jẹ́ pé àwọn àpọ́sítélì Jésù ti kú, tó sì jẹ́ pé àlìkámà ni Jésù fi àwọn ẹni àmì òróró tó ṣẹ́ kù láyé wé kì í ṣe ẹrú, nígbà náà, àwọn ańgẹ́lì ni àwọn ẹrú náà dúró fún. Nínú àkàwé yìí, Jésù pa dà sọ pé àwọn ańgẹ́lì ni àwọn akárúgbìn náà.—Mát. 13:39.