Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìpínrọ̀ 3: Ní àkókò míì, Jésù tún ṣe irú iṣẹ́ ìyanu yìí. Ó bọ́ àwọn ọkùnrin tí iye wọn tó ẹgbẹ̀rún mẹ́rin [4,000], láìka àwọn obìnrin àtàwọn ọmọdé. Ńṣe ló tún pín oúnjẹ náà “fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn, àwọn ọmọ ẹ̀yìn ẹ̀wẹ̀ fún àwọn ogunlọ́gọ̀ náà.”—Mát. 15:32-38.