Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Ìpínrọ̀ 7: Nígbà ayé Pétérù, gbogbo àwọn ‘àgùntàn kéékèèké’ tí wọ́n á máa bọ́ náà ló ní ìrètí láti lọ sí ọ̀run.