Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ìpínrọ̀ 8: Níwọ̀n bí àwọn tó ṣẹ̀ṣẹ̀ di Kristẹni ti ń “bá a lọ ní fífi ara wọn fún ẹ̀kọ́ àwọn àpọ́sítélì,” ó fi hàn pé àwọn àpọ́sítélì máa ń kọ́ àwọn èèyàn déédéé. Díẹ̀ lára ẹ̀kọ́ àwọn àpọ́sítélì yìí ló wá di ara Ìwé Mímọ́ Kristẹni Lédè Gíríìkì.