Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Ìpínrọ̀ 12: Bó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn míì tí kì í ṣe àpọ́sítélì náà rí ẹ̀bùn ẹ̀mí gbà lọ́nà ìyanu, ó jọ pé lọ́pọ̀ ìgbà, àwọn àpọ́sítélì ló máa ń fún wọn ní ẹ̀bùn ẹ̀mí yìí lọ́nà ìyanu tàbí kí wọ́n gbà á níṣojú àpọ́sítélì kan.—Ìṣe 8:14-18; 10:44, 45.