Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Tá a bá ń sọ̀rọ̀ nípa àwọn ohun tó ń mú ọkàn fà sí ìṣekúṣe, ó lè jẹ́ àwòrán tàbí ìwé tàbí orin tó dá lórí ìbálòpọ̀. Nínú àpilẹ̀kọ yìí “àwòrán oníhòòhò” ni a máa lò jù, àmọ́ ó ṣì kan àwọn ohun mìíràn, yálà èyí tí èèyàn ń kà tàbí tó ń gbọ́ tó ń mú kí ó máa wu onítọ̀hún láti ní ìbálòpọ̀.