Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ohun míì tó tún di àwátì ni Ọgbà Édẹ́nì tí Ọlọ́run dá fún àwọn òbí wa àkọ́kọ́. Ó ṣeé ṣe kí ìkún-omi ti gbá gbogbo rẹ̀ lọ. Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, a jẹ́ pé àwọn Kérúbù tí wọ́n ń ṣọ́ ẹnu ọ̀nà àbáwọlé ọgbà náà lè pa dà sí ọ̀run. Bí iṣẹ́ tí wọ́n ti ń ṣe bọ̀ láti ẹgbẹ̀jọ [1600] ọdún ṣe parí nìyẹn.—Jẹ́nẹ́sísì 3:22-24.