Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Nínú Jí! Yorùbá ti oṣù October–December 2006, tó jẹ́ ìtẹ̀jáde ẹlẹ́ẹ̀kan lóṣù mẹ́ta, a gbé mẹ́ta jáde lára àwọn àpilẹ̀kọ tó wà nínú àkànṣe ìwé ìròyìn yìí. Àwọn ni: “Ṣé Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Ta Ko Àkọsílẹ̀ Inú Jẹ́nẹ́sísì?,” “Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Mo Gbà Gbọ́ Nípa Ìṣẹ̀dá?,” àti “Ṣé Ohun Tó Bá Wù Ọ́ Lo Lè Gbà Gbọ́?”