Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọ̀rọ̀ Hébérù tá a túmọ̀ sí “omidan” ní Aísáyà 7:14 lè tọ́ka sí abilékọ tàbí wúńdíá. Nítorí ìdí yìí, a lè lo ọ̀rọ̀ náà fún ìyàwó Aísáyà àti fún ọmọbìnrin Júù kan, ìyẹn Màríà tó jẹ́ wúńdíá.