Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Nígbà yẹn lọ́hùn-ún, ọ̀pọ̀ jù lọ àwọn aṣáájú-ọ̀nà ni kì í ṣe iṣẹ́ míì yàtọ̀ sí iṣẹ́ ìwàásù. Wọ́n máa ń rí àwọn ìwé tó ṣàlàyé Bíbélì gbà ní ẹ̀dínwó, wọ́n á fún àwọn èèyàn, wọ́n á sì fi ìtìlẹ́yìn owó táwọn èèyàn bá ṣe gbọ́ bùkátà ara wọn.