Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ábíbù ni àwọn Hébérù máa ń pe oṣù àkọ́kọ́ nínú kàlẹ́ńdà wọn. Àmọ́ wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í pè é ní Nísàn lẹ́yìn tí wọ́n ti ìgbèkùn dé láti Bábílónì. Nísàn yẹn la máa lò nínú àpilẹ̀kọ yìí.