Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Nígbà tí oòrùn wọ̀, Nísàn 15 bẹ̀rẹ̀, èyí tó túmọ̀ sí pé lọ́dún yẹn, Sábáàtì (Sátidé) ti ọ̀sẹ̀ yẹn bọ́ sí ọjọ́ kan náà pẹ̀lú ọjọ́ àkọ́kọ́ Àjọyọ̀ Àkàrà Aláìwú tó sábà máa ń jẹ́ sábáàtì. Torí pé Sábáàtì méjèèjì bọ́ sí ọjọ́ kan náà, Sábáàtì yẹn jẹ́ “ọjọ́ ńlá.”—Ka Jòhánù 19:31, 42.