Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Jèhófà kò rọ òjò fún ọdún mẹ́ta àtààbọ̀, káwọn ọmọ Ísírẹ́lì lè ríi pé òrìṣà Báálì tí wọ́n gbà pé ó ń mú òjò àti ọmọ wá fún ilẹ̀ náà kò ní agbára kankan. (1 Àwọn Ọba, orí 18) Wo àpilẹ̀kọ náà “Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn” nínú Ilé Ìṣọ́ January 1 àti Ilé Ìṣọ́ April 1, 2008.