Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Jésíbẹ́lì mọ̀ pé, àwọn ọmọ Nábótì ló máa jogún ọgbà àjàrà yẹn tí bàbá wọn bá kú. Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ torí ẹ̀ ló ṣe pa wọ́n. Fún àlàyé síwájú sí i nípa ìdí tí Ọlọ́run fi fàyè gba irú ìwà ìkà bẹ́ẹ̀, wo àpilẹ̀kọ náà “Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé” nínú ìwé yìí.