Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b A lè bi ara wa pé, Báwo ni àwọn awòràwọ̀ náà ṣe mọ̀ pé “ìràwọ̀” tí wọ́n rí ní Ìlà Oòrùn ní nǹkan ṣe pẹ̀lú ìbí “ọba àwọn Júù”? Àbí wọ́n gbọ́ ìròyìn nípa ìbí Jésù nígbà tí wọ́n ń gba ilẹ̀ Ísírẹ́lì kọjá lẹ́nu ìrìn àjò wọn ni?