Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Juvenile polyarthritis jẹ́ àìsàn aromọléegun burúkú kan tó máa ń ṣe àwọn ọmọdé. Tí àìsàn yìí bá ti wọlé sí àgọ́ ara, ńṣe ni àwọn sẹ́ẹ̀lì tó ń gbógun ti àrùn nínú ara á bẹ̀rẹ̀ sí í ba àwọn iṣan ara jẹ́. Èyí máa ń fa ìrora tó bùáyà, tí oríkèé ara á sì máa wú.