Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àṣà ìbílẹ̀ lè nípa lórí irú ìtọ́jú tí òbí fẹ́ tàbí ohun tí àwọn ọmọ máa lè ṣe. Ní àwọn ibì kan, ó wọ́pọ̀ pé kí àwọn ìdílé láti ìrandíran máa gbé pọ̀ tàbí kí wọ́n máa rí ara wọn déédéé. Ohun tí àwọn kan sì fẹ́ nìyẹn.