Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Tí àwọn òbí yín bá ṣì ń dá gbé, ẹ rí i pé ẹ wá àwọn tó ṣeé fọkàn tán láti máa bójú tó wọn. Kẹ́ ẹ fún àwọn tó ń tọ́jú wọn ní kọ́kọ́rọ́ tí wọ́n fi lè ṣílẹ̀kùn bí ohun àìròtẹ́lẹ̀ bá ṣẹlẹ̀ sí àgbàlagbà náà.