Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọ̀mọ̀wé Bíbélì kan ṣàlàyé lórí ọ̀rọ̀ tí Ọlọ́run sọ nínú Ẹ́kísódù 3:14 pé: “Kò sí ohun tó lè dí i lọ́wọ́ láti ṣe ohun tó fẹ́ . . . Odi agbára ni orúkọ náà [Jèhófà] jẹ́ fún Ísírẹ́lì, ó sì tún jẹ́ orísun ìrètí àti ìtùnú tí kò nípẹ̀kun.”