Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Tó o bá fẹ́ ka ìtàn ìgbésí ayé díẹ̀ lára àwọn arákùnrin yìí, wo àwọn Ilé Ìṣọ́ tí a tọ́ka sí yìí: Thomas J. Sullivan (January 1, 1967, ojú ìwé 27); Klaus Jensen (October 1, 1970, ojú ìwé 603); Max Larson (September 1, 1989, ojú ìwé 23); Hugo Riemer (September 15, 1964 [Gẹ̀ẹ́sì]); àti Grant Suiter (March 1, 1984, ojú ìwé 23).