Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Wo àwọn àpilẹ̀kọ tá a pè ní, “Àwọn Kristẹni Ń Jọ́sìn ní Ẹ̀mí àti Òtítọ́” àti “Wọ́n Ń Bá A Lọ ní Rírìn Nínú Òtítọ́” nínú Ilé Ìṣọ́ July 15, 2002. A ti tẹ kúlẹ̀kúlẹ̀ àlàyé nípa apá ti ilẹ̀ ayé lára ètò Ọlọ́run ti òde òní jáde nínú ìwé Jehovah’s Witnesses—Proclaimers of God’s Kingdom.