Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Lára àwọn nǹkan tí wọ́n ti ṣe ni pé wọ́n ṣe ìkéde nípa ewu tó wà nínú sìgá, wọ́n fòfin de ìpolówó sìgá, wọ́n fi owó kún owó orí tí wọ́n ń san, wọ́n sì tún ṣe àwọn ètò kan láti ran àwọn tó ń mu sìgá lọ́wọ́ kí wọ́n lè jáwọ́.