Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Sìgá Mímu tí a sọ̀rọ̀ rẹ̀ níbí ń tọ́ka sí fífa èéfín tábà látara sìgá tàbí ìkòkò àtàwọn nǹkan míì tí wọ́n fi tábà ṣe. Àmọ́, ìlànà Bíbélì tí a gbé yẹ̀ wò níbí tún kan àwọn tó máa ń mu sìgá ìgbàlódé tó ń lo bátìrì tàbí àwọn tó ń jẹ ewé tábà tàbí tó ń fín áṣáà.