Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé ọ̀rọ̀ náà “mánà” wá láti inú ọ̀rọ̀ Hébérù náà “man hu’?” tó túmọ̀ sí “kí ni èyí?”