Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Bí àpẹẹrẹ, ìwé Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn ṣe àlàyé tó kún rẹ́rẹ́ nípa ìgbésí ayé àwọn ẹni mẹ́rìnlá kan tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn. Ìwé náà kò dá lórí ohun tí wọ́n ń ṣàpẹẹrẹ tàbí ìtumọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ tí wọ́n ń mú ṣẹ, kàkà bẹ́ẹ̀, ó dá lórí àwọn ẹ̀kọ́ pàtàkì tí a lè kọ́ lára wọn.