Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a A jíròrò bá a ṣe dá ẹrú olóòótọ́ àti olóye mọ̀ nínú Ilé Ìṣọ́, July 15, 2013, ojú ìwé 21 àti 22, ìpínrọ̀ 8 sí 10. Àpilẹ̀kọ tó ṣáájú èyí jíròrò bá a ṣe dá àwọn wúńdíá náà mọ̀. A ṣàlàyé àpèjúwe àgùntàn àtàwọn ewúrẹ́ nínú Ilé Ìṣọ́, October 15, 1995, ojú ìwé 23 sí 28, a sì tún jíròrò rẹ̀ nínú àpilẹ̀kọ tó kàn nínú ìwé ìròyìn yìí.