Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b “Bẹ́tẹ́lì” túmọ̀ sí “Ilé Ọlọ́run.” Orúkọ yìí làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń pe àwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì wọn kárí ayé. (Jẹ́nẹ́sísì 28:17, 19) Àwọn ìdílé Bẹ́tẹ́lì ń ṣe onírúurú iṣẹ́ láti ṣètìlẹ́yìn fún iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ tí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń ṣe.