Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àwọn alàgbà ni a dìídì kọ àpilẹ̀kọ yìí àti èyí tó tẹ̀ lé e fún, àmọ́ gbogbo wa nínú ìjọ ló yẹ ká fún ohun tá a fẹ́ jíròrò láfiyèsí. Kí nìdí? Ó máa jẹ́ kí gbogbo àwọn ọkùnrin tó ti ṣèrìbọmi mọ̀ pé ó yẹ káwọn gba ìdálẹ́kọ̀ọ́ kí wọn bàa lè ṣèrànwọ́ láti bójú tó iṣẹ́ nínú ìjọ. Ìdálẹ́kọ̀ọ́ yìí sì máa wá ṣe gbogbo èèyàn láǹfààní.