Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Tá a bá sọ pé ẹni méjì ní àjọṣe, ohun tá à ń sọ ni ọwọ́ táwọn méjèèjì fi mú ara wọn àti bí wọ́n ṣe ń hùwà síra wọn. Àwọn méjèèjì lọ̀rọ̀ náà kàn.