Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àwọn kan ò gba Bíbélì gbọ́ torí pé wọn kò fara mọ́ àwọn ẹ̀kọ́ tí àwọn oníṣọ́ọ̀ṣì fi kọ́ni láyé àtijọ́ àti èyí tí wọ́n fi ń kọ́ni lóde òní. Ọ̀kan lára irú àwọn ẹ̀kọ́ bẹ́ẹ̀ ni pé ńṣe ni oòrùn, òṣùpá àti gbogbo àwọn ìràwọ̀ ń yí ayé po. Wọn ò tún fara mọ́ ẹ̀kọ́ náà pé ọjọ́ mẹ́fà tó jẹ́ wákàtí mẹ́rìnlélógún péré ni Ọlọ́run fi dá ayé.—Wo àpótí náà “Bí Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Ṣe Bá Bíbélì Mu.”