Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Míṣọ́nnárì kan tórúkọ rẹ̀ ń jẹ́ John Hunt, tú èyí tó pọ̀ jù nínú Májẹ̀mú Tuntun sí èdè Fijian, ó sì tẹ̀ ẹ́ jáde lọ́dún 1847. Ìtumọ̀ Bíbélì yìí kò ṣeé fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn torí ó lo orúkọ Ọlọ́run, ìyẹn “Jiova” nínú Máàkù 12:36, Lúùkù 20:42 àti Ìṣe 2:34.