Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé d Sáàmù 45 pẹ̀lú sọ̀rọ̀ nípa bí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣe máa wáyé ní ṣísẹ̀-n-tẹ̀lé. Ọba máa kọ́kọ́ jagun, lẹ́yìn yẹn ni ìgbéyàwó náà á wáyé.