Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìlú Fílípì wà lára àwọn ìlú tí Róòmù ń ṣàkóso. Ó ṣeé ṣe kí àwọn kan lára àwọn tó wà nínú ìjọ náà ti ní ẹ̀tọ́ kan tàbí òmíràn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìlú Róòmù. Èyí sì mú kí wọ́n ní àwọn àǹfààní kan tí àwọn ará tó kù ò ní.