Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọ̀rọ̀ Hébérù náà “Ṣìọ́ọ̀lù” àti ti Gíríìkì náà “Hédíìsì” túmọ̀ sí “Sàréè.” Àwọn ìtumọ̀ Bíbélì míì pè é ní “ọ̀run àpáàdì,” àmọ́ ẹ̀kọ́ pé èèyàn máa ń joró nínú ọ̀run àpáàdì kò bá Bíbélì mu.