Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ìgbà méjì ni Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa ogun yìí. Àkọ́kọ́ wà nínu ìwé Àwọn Onídàájọ́ orí 4, èkejì sì wà nínú orin tí Dèbórà àti Bárákì kọ ní orí 5. Ńṣe ni orí méjèèjì yìí so kọ́ra torí pé ọ̀kọ̀ọ̀kan ṣe àlàyé tí èkejì kò ṣe.