Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Tó o bá fẹ́ mọ̀ nípa àwọn tó fi irú ìgbàgbọ́ bẹ́ẹ̀ hàn, lọ ka ìtàn ìgbésí ayé Lillian Gobitas Klose (Jí! July 22, 1993, ojú ìwé 12 sí 17), Feliks Borys (Jí! February 22, 1994, ojú ìwé 20 sí 23) àti Brunella Inconditi, bí àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ṣe sọ ọ́ (Ilé-Ìṣọ́nà July 1, 1994, ojú ìwé 29 sí 31).