b Tímótì gbà pé kí wọ́n dádọ̀dọ́ fún òun bí Pọ́ọ̀lù ṣe sọ. Èyí kì í ṣe torí pé ó pọn dandan pé kí àwọn Kristẹni dádọ̀dọ́, àmọ́ ó jẹ́ nítorí pé Pọ́ọ̀lù kò fẹ́ kí àwọn Júù tí wọ́n máa wàásù fún ní ìdí kankan láti máa rí sí Tímótì tí bàbá rẹ̀ jẹ́ Kèfèrí.—Ìṣe 16:3.