Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìwé Fivefold Psalter pín ìwé Sáàmù sí ọ̀nà márùn-ún, ó sì tún ní apá kan tí wọ́n fi to àwọn orúkọ òye tí wọ́n fi ń pe Ọlọ́run àti lẹ́tà Hébérù mẹ́rin tó dúró fún orúkọ Ọlọ́run.