Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ètò Ọlọ́run ló dábàá yìí nínú Ìdìpọ̀ Kẹfà ìwé Millennial Dawn (ọdún 1904) àti nínú ìwé ìròyìn Zion’s Watch Tower ti oṣù August ọdún 1906, lédè Jámánì. Àmọ́, nínú ìwé ìròyìn The Watch Tower toṣù September, ọdún 1915, ètò Ọlọ́run la àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lóye pé kò yẹ kí wọ́n dá sọ́rọ̀ ogun mọ́ rárá. Ṣùgbọ́n àpilẹ̀kọ yẹn kò jáde lédè Jámánì.