Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Lákọ̀ọ́kọ́, Ábúrámù àti Sáráì lorúkọ wọn, àmọ́ orúkọ tí Jèhófà sọ wọ́n ló wá mọ́ wọn lórí.—Jẹ́nẹ́sísì 17:5, 15.