Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọ̀pọ̀ máa ń fúnni lẹ́bùn nígbà tí ẹnì kan bá ń ṣe ọjọ́ ìbí àti lásìkò ọdún. Àmọ́ àwọn nǹkan táwọn èèyàn sábà máa ń ṣe lásìkò tí wọ́n bá ń ṣe ayẹyẹ yìí ni ó ta ko ohun tí Bíbélì fi kọ́ni. Wo àpilẹ̀kọ tó ní àkòrí náà “Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé—Ṣé Ó Yẹ Káwọn Kristẹni Máa Ṣe Ọdún Kérésìmesì?” nínú ìwé ìròyìn yìí.