Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Gbàrà tí àwọn tó ń wá ibi ìsádi bá ti dé, kí àwọn alàgbà tẹ̀ lé ìtọ́ni tó wà nínú A Ṣètò Wa Láti Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà, orí 8, ìpínrọ̀ 30. Àwọn alàgbà lè kàn sáwọn ìjọ tó wà lórílẹ̀-èdè míì nípa kíkọ lẹ́tà sí ẹ̀ka ọ́fíìsì ti wọn lórí ìkànnì jw.org. Àmọ́ bí wọ́n ṣe ń ṣe ìwádìí yẹn lọ, wọ́n lè fọgbọ́n béèrè lọ́wọ́ ẹni náà nípa ìjọ rẹ̀ àtàwọn nǹkan míì tó jẹ mọ́ iṣẹ́ ìsìn rẹ̀, kí wọ́n lè mọ bó ṣe ń ṣe sí nínú ìjọ.