Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Orí mẹ́ẹ̀ẹ́dógún [15] nínú ìwé Jẹ́nẹ́sísì ló dá lórí ìtàn Ábúráhámù. Yàtọ̀ síyẹn, àádọ́rin [70] ìgbà ni wọ́n sọ̀rọ̀ nípa Ábúráhámù nínú Ìwé Mímọ́ Kristẹni Lédè Gíríìkì.