Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìwé kan tí àjọ National Health Service lórílẹ̀-èdè England gbé jáde sọ pé: “IUD oníkọ́pà gbẹ́ṣẹ́ gan-an, tipátipá la fi ń rí àwọn tí kò ṣiṣẹ́ fún. Ohun tí èyí túmọ̀ sí ni pé nínú ọgọ́rùn-ún [100] obìnrin tó ń lo IUD, tipátipá ni wọ́n fi máa ń rí obìnrin kan tó lóyún láàárín ọdún kan. Bí kọ́pà inú IUD náà bá ṣe pọ̀ tó, bẹ́ẹ̀ náà ló ṣe máa gbéṣẹ́ tó.”