Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú ìkànnì wa, ohun kan wà tá a pè ní Study Guides tó ń mú kó rọrùn láti lóye àwọn ẹ̀kọ́ tó wà nínú ìwé “Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? “ Àrànṣe gidi ló jẹ́ láti kọ́ tọmọdé tàgbà lẹ́kọ̀ọ́ òtítọ́. Ó wà ní onírúurú èdè. Wàá rí i lórí Ìkànnì jw.org, lábẹ́ abala BIBLE TEACHINGS > BIBLE STUDY TOOLS.