Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́ kí wọ́n lè túbọ̀ lóye Ìwé Mímọ́. Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i nípa ẹ̀kọ́ Bíbélì yìí, a rọ̀ ẹ́ pé kó o wo fídíò tá a pè ní Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? Wàá rí i lórí ìkànnì wa, ìyẹn jw.org/yo.