Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b A ti fi Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere Ìjọba Ọlọ́run rọ́pò ilé ẹ̀kọ́ yìí. Àwọn òjíṣẹ́ alákòókò kíkún tó ń sìn lórílẹ̀-èdè míì tí wọ́n sì kúnjú ìwọ̀n lè gba fọ́ọ̀mù ilé ẹ̀kọ́ náà kí wọ́n sì lọ gba ìdálẹ́kọ̀ọ́ lórílẹ̀-èdè wọn tàbí lórílẹ̀-èdè míì tó ń sọ èdè wọn.