Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Olùjọ́sìn Jèhófà ni Lámékì bàbá Nóà, àmọ́ ọdún márùn-ún ṣáájú Ìkún Omi ló ti kú. Torí náà, ká tiẹ̀ ní màmá Nóà, àwọn ẹ̀gbọ́n Nóà àtàwọn àbúrò rẹ̀ bá ṣì wà láyé nígbà yẹn, ó dájú pé wọn ò la Ìkún Omi yẹn já.