Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bíbélì jẹ́ ká mọ̀ pé àwọn áńgẹ́lì kan ní orúkọ. (Oníd. 13:18; Dán. 8:16; Lúùkù 1:19; Ìṣí. 12:7) Níwọ̀n ìgbà tó jẹ́ pé ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ìràwọ̀ ni Jèhófà fún lórúkọ (Sm. 147:4), ó bọ́gbọ́n mu láti gbà pé gbogbo àwọn áńgẹ́lì ló ní orúkọ, tó fi mọ́ áńgẹ́lì tó sọ ara rẹ̀ di Sátánì.